Samuẹli Kinni 31:12 BM

12 àwọn tí wọ́n jẹ́ akọni ninu wọ́n lọ sí Beti Ṣani lóru, wọ́n sì gbé òkú Saulu ati ti àwọn ọmọ rẹ̀ kúrò lára odi Beti Ṣani, wá sí Jabeṣi Gileadi, wọ́n sì sin wọ́n sibẹ.

Ka pipe ipin Samuẹli Kinni 31

Wo Samuẹli Kinni 31:12 ni o tọ