Samuẹli Kinni 31:2 BM

2 Ṣugbọn àwọn ará Filistia lé Saulu ati àwọn ọmọ rẹ̀. Wọ́n pa Jonatani ati Abinadabu ati Malikiṣua, àwọn ọmọ Saulu.

Ka pipe ipin Samuẹli Kinni 31

Wo Samuẹli Kinni 31:2 ni o tọ