Samuẹli Kinni 4:14 BM

14 Nígbà tí Eli gbọ́ igbe wọn, ó bèèrè pé, “Kí ni wọ́n ń kígbe báyìí fún?” Ọkunrin náà bá yára wá sọ ohun tí ó ṣẹlẹ̀ fún Eli.

Ka pipe ipin Samuẹli Kinni 4

Wo Samuẹli Kinni 4:14 ni o tọ