Samuẹli Kinni 4:16 BM

16 Ọkunrin náà wí fún un pé, “Ojú ogun ni mo ti sá wá lónìí.”Eli bá bi í pé, “Kí ló dé, ọmọ mi?”

Ka pipe ipin Samuẹli Kinni 4

Wo Samuẹli Kinni 4:16 ni o tọ