Samuẹli Kinni 4:20 BM

20 Bí ó ti ń kú lọ, àwọn obinrin tí wọn ń gbẹ̀bí rẹ̀ wí fún un pé, “Ṣe ọkàn gírí, ọkunrin ni ọmọ tí o bí.” Ṣugbọn kò tilẹ̀ kọ ibi ara sí ohun tí wọ́n sọ, kò sì dá wọn lóhùn.

Ka pipe ipin Samuẹli Kinni 4

Wo Samuẹli Kinni 4:20 ni o tọ