7 ẹ̀rù ba àwọn ará Filistia. Wọ́n ní, “Oriṣa kan ti dé sí ibùdó wọn! A gbé! Irú èyí kò ṣẹlẹ̀ rí.
Ka pipe ipin Samuẹli Kinni 4
Wo Samuẹli Kinni 4:7 ni o tọ