1 Lẹ́yìn tí àwọn ará Filistia gba àpótí Ọlọrun lọ́wọ́ àwọn ọmọ Israẹli, wọ́n gbé e láti Ebeneseri lọ sí Aṣidodu.
Ka pipe ipin Samuẹli Kinni 5
Wo Samuẹli Kinni 5:1 ni o tọ