Samuẹli Kinni 6:19 BM

19 Aadọrin ninu àwọn ará ìlú Beti Ṣemeṣi ni OLUWA pa, nítorí pé, wọ́n yọjú wo inú àpótí OLUWA náà. Àwọn eniyan náà sì ṣọ̀fọ̀ nítorí pé OLUWA pa ọpọlọpọ ninu wọn.

Ka pipe ipin Samuẹli Kinni 6

Wo Samuẹli Kinni 6:19 ni o tọ