Samuẹli Kinni 7:10 BM

10 Nígbà tí Samuẹli ń rúbọ lọ́wọ́, àwọn ará Filistia ń súnmọ́ ọ̀dọ̀ àwọn ọmọ Israẹli, láti bá wọn jagun. Ṣugbọn OLUWA sán ààrá lù wọ́n láti ọ̀run wá. Ìdààmú bá wọn, wọ́n sì túká pẹlu ìpayà.

Ka pipe ipin Samuẹli Kinni 7

Wo Samuẹli Kinni 7:10 ni o tọ