Samuẹli Kinni 7:17 BM

17 Lẹ́yìn náà, yóo pada lọ sí ilé rẹ̀, ní Rama, nítorí pé a máa dájọ́ fún àwọn eniyan níbẹ̀ pẹlu. Ó sì tẹ́ pẹpẹ kan sibẹ fún OLUWA.

Ka pipe ipin Samuẹli Kinni 7

Wo Samuẹli Kinni 7:17 ni o tọ