5 Samuẹli ní kí wọ́n kó gbogbo eniyan Israẹli jọ sí Misipa, ó ní òun óo gbadura sí OLUWA fún wọn níbẹ̀.
Ka pipe ipin Samuẹli Kinni 7
Wo Samuẹli Kinni 7:5 ni o tọ