14 Yóo gba ilẹ̀ oko yín tí ó dára jùlọ ati ọgbà àjàrà ati ti olifi yín, yóo sì fi fún àwọn iranṣẹ rẹ̀.
Ka pipe ipin Samuẹli Kinni 8
Wo Samuẹli Kinni 8:14 ni o tọ