Samuẹli Kinni 8:16 BM

16 Yóo gba àwọn iranṣẹkunrin ati iranṣẹbinrin yín, ati àwọn mààlúù ati kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́ yín tí wọ́n dára jùlọ, yóo máa kó wọn ṣiṣẹ́.

Ka pipe ipin Samuẹli Kinni 8

Wo Samuẹli Kinni 8:16 ni o tọ