Samuẹli Kinni 8:19 BM

19 Ṣugbọn àwọn eniyan náà kọ̀, wọn kò gba ohun tí Samuẹli wí gbọ́. Wọ́n ní, “Rárá o! A ṣá fẹ́ ní ọba ni.

Ka pipe ipin Samuẹli Kinni 8

Wo Samuẹli Kinni 8:19 ni o tọ