21 Nígbà tí Samuẹli gbọ́ gbogbo ohun tí wọ́n wí, ó lọ sọ fún OLUWA.
Ka pipe ipin Samuẹli Kinni 8
Wo Samuẹli Kinni 8:21 ni o tọ