Samuẹli Kinni 8:6 BM

6 Ọ̀rọ̀ náà kò dùn mọ́ Samuẹli ninu, pé àwọn eniyan náà ní kí ó fi ẹnìkan jọba lórí wọn. Samuẹli bá gbadura sí OLUWA.

Ka pipe ipin Samuẹli Kinni 8

Wo Samuẹli Kinni 8:6 ni o tọ