9 Nítorí náà, gbọ́ tiwọn, ṣugbọn kìlọ̀ fún wọn gidigidi, kí o sì ṣe àlàyé gbogbo ohun tí ọba náà yóo máa ṣe sí wọn fún wọn dáradára.”
Ka pipe ipin Samuẹli Kinni 8
Wo Samuẹli Kinni 8:9 ni o tọ