1 Ọba 15:12 BMY

12 Ó sì mú àwọn tí ń ṣe panṣágà kúrò ní ilẹ̀ náà, ó sì kó gbogbo ère tí àwọn baba rẹ̀ ti ṣe kúrò.

Ka pipe ipin 1 Ọba 15

Wo 1 Ọba 15:12 ni o tọ