1 Ọba 15:13 BMY

13 Ó sì mú Máákà ìyá ìyá rẹ̀ kúrò láti máa ṣe ayaba, nítorí tí ó yá ère kan fún òrìṣà rẹ̀. Áṣà sì ké ère náà lulẹ̀, ó sì dáná sun ún níbi odò Kídírónì.

Ka pipe ipin 1 Ọba 15

Wo 1 Ọba 15:13 ni o tọ