1 Ọba 19:7 BMY

7 Ańgẹ́lì Olúwa sì tún padà wá lẹ́ẹ̀kejì, ó sì tún fi ọwọ́ tọ́ ọ, ó sì wí pé, “Dìde, kí ó jẹun, nítorí ìrìnàjò náà jìn fún ọ.”

Ka pipe ipin 1 Ọba 19

Wo 1 Ọba 19:7 ni o tọ