1 Ọba 19:8 BMY

8 Ó si dide, ó sì jẹ, ó mu, o sì fi agbára oúnjẹ yìí lọ ní ogójì ọ̀sán àti ogójì òru sí Hórébù, òkè Ọlọ́run.

Ka pipe ipin 1 Ọba 19

Wo 1 Ọba 19:8 ni o tọ