1 Ọba 2:27 BMY

27 Bẹ́ẹ̀ ni Sólómónì yọ Ábíátarì kúrò nínú iṣẹ́ àlùfáà Olúwa, kí ó lè mú ọ̀rọ̀ Olúwa tí ó ti sọ nípa ilé Élì ní Ṣílò ṣẹ.

Ka pipe ipin 1 Ọba 2

Wo 1 Ọba 2:27 ni o tọ