1 Ọba 22:10 BMY

10 Ọba Ísírẹ́lì àti Jèhóṣáfátì ọba Júdà jókòó lórí ìtẹ́ wọn, wọ́n wọ aṣọ ìgúnwà wọn ní ìta ẹnubodè Samáríà, gbogbo àwọn wòlíì náà sì ń sọtẹ́lẹ̀ níwájú wọn.

Ka pipe ipin 1 Ọba 22

Wo 1 Ọba 22:10 ni o tọ