1 Ọba 22:11 BMY

11 Ṣedekíà ọmọ Kénáánà sì ṣe ìwo irin fún ara rẹ̀, ó sì wí pé, “Báyìí ni Olúwa wí: ‘Wọ̀nyí ni ìwọ yóò fi kan àwọn ará Árámù títí ìwọ yóò fi run wọ́n.’ ”

Ka pipe ipin 1 Ọba 22

Wo 1 Ọba 22:11 ni o tọ