1 Ọba 8:51 BMY

51 nítorí ènìyàn rẹ àti ìní rẹ ni wọ́n, àwọn ẹni tí ìwọ ti mú ti Éjíbítì jáde wá, láti inú irin ìléru.

Ka pipe ipin 1 Ọba 8

Wo 1 Ọba 8:51 ni o tọ