2 Ọba 11:10 BMY

10 Nígbà náà, ó fún àwọn olórí ní àwọn ọ̀kọ̀ àti àwọn apata tí ó ti jẹ́ ti ọba Dáfídì tí ó sì wà nínú ilé tí a kọ́ fún Olúwa.

Ka pipe ipin 2 Ọba 11

Wo 2 Ọba 11:10 ni o tọ