2 Ọba 14:21 BMY

21 Nígbà náà, gbogbo àwọn ènìyàn Júdà mú Ásáríyà tí ó jẹ́ ọmọ ọdún mẹ́rìndínlógún. Wọ́n sì ṣe é ní ọba ní ìrọ́pò baba rẹ̀ Ámásáyà.

Ka pipe ipin 2 Ọba 14

Wo 2 Ọba 14:21 ni o tọ