2 Ọba 14:22 BMY

22 Òun ni ẹni tí ó tún Élátì kọ́, ó sì dá a padà sí Júdà lẹ́yìn tí Ámásáyà ti sinmi pẹ̀lú àwọn baba rẹ̀.

Ka pipe ipin 2 Ọba 14

Wo 2 Ọba 14:22 ni o tọ