2 Ọba 15:11 BMY

11 Fún ti ìyókù iṣẹ́ nígbà ìjọba Ṣakaríà. Wọ́n kọ ọ́ sínú ìwé ìtàn ayé àwọn ọba Ísírẹ́lì.

Ka pipe ipin 2 Ọba 15

Wo 2 Ọba 15:11 ni o tọ