2 Ọba 15:12 BMY

12 Bẹ́ẹ̀ ni ọ̀rọ̀ Olúwa tí a sọ fún Jéhù jẹ́ ìmúṣẹ: “Àwọn ọmọ rẹ̀ yóò jókòó lórí ìtẹ́ Ísírẹ́lì títí dé ìran kẹrin.”

Ka pipe ipin 2 Ọba 15

Wo 2 Ọba 15:12 ni o tọ