2 Ọba 15:27 BMY

27 Ní ọdún kejìléláàdọ́ta Ásáríyà ọba Júdà, Pékà ọmọ Rèmálíà di ọba Ísírẹ́lì ní Ṣamáríà. Ó sì jọba fún ogún ọdún.

Ka pipe ipin 2 Ọba 15

Wo 2 Ọba 15:27 ni o tọ