2 Ọba 15:28 BMY

28 Ó sì ṣe búburú lójú Olúwa, kò sì yípadà kúrò nínú ẹ̀ṣẹ̀ Jéróbóámù ọmọ Nébátì, èyí tí ó fa Ísírẹ́lì láti dá.

Ka pipe ipin 2 Ọba 15

Wo 2 Ọba 15:28 ni o tọ