2 Ọba 15:31 BMY

31 Fún ti ìyókù iṣẹ́ nígbà ìjọba Pékà, àti gbogbo ohun tí ó ṣe, ṣé a kò kọ wọ́n sínú ìwé ìtàn ayé àwọn ọba Ísírẹ́lì?

Ka pipe ipin 2 Ọba 15

Wo 2 Ọba 15:31 ni o tọ