2 Ọba 15:32 BMY

32 Ní ọdún keje Pékà ọmọ Remalíà ọba Ísírẹ́lì, Jótamù ọmọ Ùsáyà ọba Júdà bẹ̀rẹ̀ sí ní jọba.

Ka pipe ipin 2 Ọba 15

Wo 2 Ọba 15:32 ni o tọ