2 Ọba 16:13 BMY

13 Ó sì ṣun ẹbọ ọrẹ-ṣíṣun rẹ̀ àti ọrẹ-jíjẹ rẹ̀, o si ta ohun-mímu rẹ̀ sílẹ̀, ó sì wọ́n èjẹ̀ ọrẹ-àlàáfíà rẹ̀ sí ará pẹpẹ náà.

Ka pipe ipin 2 Ọba 16

Wo 2 Ọba 16:13 ni o tọ