2 Ọba 16:14 BMY

14 Ṣùgbọ́n ó mú pẹpẹ idẹ tí ó wà níwájú Olúwa kúrò láti iwájú ilé náà, láti àárin méjì pẹpẹ náà, àti ilé Olúwa, ó sì fi í sí apá àríwá pẹpẹ náà.

Ka pipe ipin 2 Ọba 16

Wo 2 Ọba 16:14 ni o tọ