2 Ọba 16:6 BMY

6 Ní àkókò náà, Résínì Ọba Ṣíríà gba Élátì padà fún Ṣíríà, ó sì lé àwọn ènìyàn Júdà kúrò ní Élátì: àwọn ará Ṣíríà sì wá sí Élíátì, wọ́n sì ń gbé ibẹ̀ títí di òní yìí.

Ka pipe ipin 2 Ọba 16

Wo 2 Ọba 16:6 ni o tọ