2 Ọba 16:5 BMY

5 Nígbà náà ni Résínì ọba Ṣíríà àti Pẹ́kà ọmọ Rèmálíà ọba Ísíráẹ́lì gòkè wá sí Jérúsálẹ́mù láti jagun: wọ́n dó ti Áhásì, ṣùgbọ́n wọn kò lè borí rẹ̀.

Ka pipe ipin 2 Ọba 16

Wo 2 Ọba 16:5 ni o tọ