2 Ọba 17:30 BMY

30 Bẹ́ẹ̀ ni àwọn ọkùnrin láti Bábílónì ṣe àgọ́ àwọn wúndíá, àwọn ọkùnrin láti Kútì ṣe Négálì, àti àwọn ènìyàn láti Hámátì ṣe Áṣímà;

Ka pipe ipin 2 Ọba 17

Wo 2 Ọba 17:30 ni o tọ