2 Ọba 17:31 BMY

31 Àti àwọn ará Áfà ṣe Nébíhásì àti Tárítakì, àti àwọn ará Ṣéfárífáímù ṣun àwọn ọmọ wọn níná gẹ́gẹ́ bí ẹbọ sí Adiramélékì àti Anamélékì, àwọn òrìṣà Ṣéfárfáímù.

Ka pipe ipin 2 Ọba 17

Wo 2 Ọba 17:31 ni o tọ