2 Ọba 17:33 BMY

33 Wọ́n sin Olúwa ṣùgbọ́n wọ́n sin òrìṣà wọn ní ìṣọ̀kan pẹ̀lú àṣà orílẹ̀ èdè wọn láti ibi tí wọ́n ti gbé wọn wá.

Ka pipe ipin 2 Ọba 17

Wo 2 Ọba 17:33 ni o tọ