2 Ọba 18:35 BMY

35 Ta ni nínú gbogbo àwọn òrìṣà ilẹ̀ yìí tí ó ti gbìyànjú láti gba ilẹ̀ rẹ̀ kúrò lọ́wọ́ mi? Báwo ni Olúwa yóò ṣe gba Jérúsálẹ́mù kúrò lọ́wọ́ mi?”

Ka pipe ipin 2 Ọba 18

Wo 2 Ọba 18:35 ni o tọ