2 Ọba 18:36 BMY

36 Ṣùgbọ́n gbogbo àwọn ènìyàn náà dákẹ́ síbẹ̀ wọn kò sì sọ ohunkóhun, láti fi fèsì, nítorí ọba ti paláṣẹ, “Ẹ má ṣe dáa lóhùn.”

Ka pipe ipin 2 Ọba 18

Wo 2 Ọba 18:36 ni o tọ