2 Ọba 2:19 BMY

19 Àwọn ọkùnrin ìlú wí fún Èlíṣà, pé “Wò ó, Olúwa wa, ìtẹ̀dó ìlú yìí dára, gẹ́gẹ́ bí o ti rí i, ṣùgbọ́n omi náà kò dára ilẹ̀ náà sì jẹ́ aṣálẹ̀.”

Ka pipe ipin 2 Ọba 2

Wo 2 Ọba 2:19 ni o tọ