20 Ó sì wí pé, “Mú àwokòtò tuntun fún mi wá, kí o sì mú iyọ̀ sí inú rẹ̀.” Wọ́n sì gbé e wá fún un.
Ka pipe ipin 2 Ọba 2
Wo 2 Ọba 2:20 ni o tọ