2 Ọba 24:17 BMY

17 Ó sì mú Mátanáyà arákùnrin baba Jéhóíákínì, ọba ní ìlú rẹ̀ ó sì yí orúkọ rẹ̀ padà sí Ṣedekáyà.

Ka pipe ipin 2 Ọba 24

Wo 2 Ọba 24:17 ni o tọ