2 Ọba 25:26 BMY

26 Nítorí èyí, gbogbo àwọn ènìyàn láti ẹni kékeré títí dé ẹni ńlá, àti pẹ̀lú àwọn olórí ogun, sá lọ si Éjíbítì nítorí ẹ̀rù àwọn ará Bábílónì.

Ka pipe ipin 2 Ọba 25

Wo 2 Ọba 25:26 ni o tọ