2 Ọba 25:27 BMY

27 Ní ọdún kẹtàdínlógójì tí a lé Jéhóíákínì ọba Júdà kúrò nílú, ní ọdún tí Efili-Méródákì di ọba Bábílónì, ó tú Jéhóíákínì kúrò nínú túbú ní ọjọ́ kẹtàdínlógbọ̀n oṣú kéjìlá.

Ka pipe ipin 2 Ọba 25

Wo 2 Ọba 25:27 ni o tọ