2 Ọba 8:28 BMY

28 Áhásáyà sì lọ pẹ̀lú Jórámù ọmọ Áhábù lọ sí ogun lórí Hásáélì ọba Árámù ní Ramoti-Gílíádì. Àwọn ará Ṣíríà ṣẹ́ Jórámù lẹ́sẹ̀.

Ka pipe ipin 2 Ọba 8

Wo 2 Ọba 8:28 ni o tọ