Ísíkẹ́lì 1:17 BMY

17 Àwọn kẹ̀kẹ́ yìí ń yí bí wọ́n ti ń yí, wọ́n ń lọ tààrà síbi tí ọ̀kọ̀ọ̀kan àwọn ẹ̀dá alààyè kọjú sí, kẹ̀kẹ́ wọn kò sì yapa bí àwọn ẹ̀dá náà ti n lọ.

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 1

Wo Ísíkẹ́lì 1:17 ni o tọ